I love learning languages. All types. Right now I am learning Yoruba. Learning a tonal language is a new thing for me, but I am in it for the long haul. My class is now at the half-way point. I can tell you a bit about myself.
Nípa Ara Mi: Orukọ mi ni Hethur, sugbon orukọ kilasi Yorùbá mi ni Titilayo. Mo n gbe ni ilu Columbus ni ipinle Ohio. Ọmọ ìlú Amẹrika ni. Télé mo gbe awon ipinle New York ati ipinle Illinois. Télé mo gbe tun orilẹ-ede Gambia. Bi agbalagba mo wa inpinle Ohio fún yunifasiti. Mo gbe Columbus awon odun ewa.
Mo feran lati se Columbus nitori pe ilu kò tobi kò kekere. Mo le ra ounge Afirika ati awon epanu fún omo mi. Tun mo le wakọ si ibi ise ati ọpọlọpọ ibi ni ogún iseju tabi iseju arundinlogbon.
Eniyan maa sọ pé mo je òṣìṣẹ́ takuntakun sugbon pé mo je alagidi kekere. Mo feran láti se ounje. Mo feran láti luwée. Mo ko feran jókòó jéjé.
Mo ní ọkọ ati omobinrin mẹta. Oruko àkọ́bí mi ni O. Keji ni E. Àbígbẹ̀yìn, ọmọ kekere, mi ni A. Ọpọlọpọ ninu ẹbi mi fẹran láti ṣere boolu aagbon, sugbon mo feran láti wo boolu aagbon.
Leave a Reply